Living Water
Yoruba Version
Ẹya Yorùbá
Oct
04
Omi Iye
Gbigbe Awon Aye Ro, Sisafihan Kristi
Omi Iye
Gbigbe Awon Aye Ro, Sisafihan Kristi
Ojo Aiku (Sunday), October 4, 2026
Orin: I.O.I CAC 567 · Ka: Owe 22:1-6
Awon Akosori / Ese Iranti
“To omode ni ona ti yoo to: nigba ti o si dagba tan, ki yoo kuro ninu re” (Owe 22:6)
Itupale
A won oluko maa n ko ipa to yato ati eyi to se pataki ninu gbigbe iwa ju awon aye ro ati mimu awon ojo rekoja ti o dara dagba. Ipa won tayo fowo to wokan eto eko nikan; ipa won n se akosori wa ran wa leti pelu ogbon ati ife. Lati to iran to n bo sona pelu ogbon ati ife.
Awon Koko Adura
- Oluwa, O seun fun awon oluko ti a ro lagbara lati maa tun awon aye se pelu ife ati ogbon.
- Baba, fun awon oluko wa ni o ni suuru lati safihan ife Re ati lati ru okun nigba gbo gbo bi Dafidi Olorun Alagbara, bukun awon oluko pelu ayo ati imuse ninu ipe won.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Nahum 1-3
Oct
03
Omi Iye
Ile Ifowopamo Agbaayanu
Omi Iye
Ile Ifowopamo Agbaayanu
Ojo Abameta (Saturday), October 3, 2026
Orin: I.O.I CAC 855 · Ka: Matiu 17:24-27
Awon Akosori / Ese Iranti
“Sugbon Olorun mi yoo pese ni kikun fun gbogbo aini yin, gege bi oro Re ninu ogo ninu Kristi Jesu” (Filipi 4:19)
Itupale
Gege bi o ti wa ni igbaani, awon iyanu Olorun si wa sibe titi di oni. Awon ise iyanu je isele ti a ko le e se alaye ni kikun fun abere, ko ti si eniyan kan nipa iseda ti a ti tabi mu owo jade lati enu eja. Ni isapeere, lati gba owo lade, a nilo lati lo ile ifowopamo, tabi a lo iloro igbalode ti o ba te ki a lo ilana awon ero POS. Sugbon lorun julo bii Peteru ni iriri ise iyanu pelu ase Jesu - o gba owo jade lati enu eja.
Awon Koko Adura
- Jesu Oluwa, ro mi lagbara lati je ki awon ilekun iyanu ibukum ati iranlow o si fun mi.
- Jesu Oluwa, ran mi lowo lati je ni iriri ni iriri ile is e itwe ati Ijo Aposteli Kristi, lagbara, alaga, awon omo igbimo ati awon osise, ile ise yi de ebute giga, ni oruko Jesu.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Mika 7-Nahum 1-3
Oct
02
Omi Iye
Ibukun Fun Iran
Omi Iye
Ibukun Fun Iran
Ojo Eti (Friday), October 2, 2026
Orin: I.O.I CAC 432 · Ka: 1 Kronika 29:10-13
Awon Akosori / Ese Iranti
“Ododo ni i gbe orile-ede leke; sugbon ese ni egan orile-ede” (Owe 14:34)
Itupale
N i aye, a korajopo lati sajoyo irin ajo ti o mu ni akoko Naijiria. Ni oni, e je ki a duro de ki a ronu lori ko wa o mu de akoko yii. Gbo gbo inu rere Re ni o n mu ki eyikeyi orile ede ati pe idajo ododo ati inu rere Re ni o n mu ki eyikeyi orile ede maa dupe fun - awon ibukun ati itesiwaju ede orile-ede yi. Sugbon bi awa naa, gege bi enikookan ati gege bi orile-ede ti o duro sin sin ninu otito ati ododo.
Awon Koko Adura
- Oluwa, O seun fun ibi ti O mu orile-ede wa de. Bukun fun wa ki O si gbe orile-ede wa yi pelu otito innu dide ati pe Re wa ti ye leke gbo gbo.
- Baba, gbo adari ti ye Re wa ti ye leke gbo gbo.
- Oluwa, labo oore-o gbo na Re ki o si wa pa gege bi okan, labo oore-o gipagona Re.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Mika 4-6
Oct
01
Omi Iye
Sise Ajoyo Ominira Ati Ojuse
Omi Iye
Sise Ajoyo Ominira Ati Ojuse
Ojobo (Thursday), October 1, 2026 (Ayajo Ojo Ominira Naijiria)
Orin: I.O.I CAC 431 · Ka: Galatia 5:1
Awon Akosori / Ese Iranti
“Nibiti Emi Oluwa ba si wa, nibe ni ominira gbe wa” (2 Korinti 3:17)
Itupale
Ojo oni je ojo pataki ninu itan orile ede wa. Naijiria, gege bi a ti tun wa lati duro die ki a si ro o lori ominira ti a ti ja fun ti a si gba lori ominira ti o tun je iwon ojus e ti o mura ni mu wa. Gege bi Naijiria ti gba ominira re nipase takuntakun, rubo ati iforiti, bakan naa ni awa, gege bi olododo ni Jesu Kristi.
Awon Koko Adura
- Oluwa, O seun fun Ominira ti a ni jegbadun ni orile-ede ni ninu Kristi, a gbadura pe a koni fowo yepere mu um.
- Baba, bukun orile-ede Naijiria pelu alafia, isokan, dide ati ayo.
- Oluwa, ran mi lowo gbe igbe ti o n bola fun imo omiwa-bi-Olorun. Oluwa, ki lo pelu ogbon ki n si maa se awon ipeju ati iwure.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Mika 1-3
Sep
30
Omi Iye
Dide Fun Iranlowo Wa
Omi Iye
Dide Fun Iranlowo Wa
Ojooru (Wednesday), September 30, 2026
Orin: I.O.I CAC 399 · Ka: Orin Dafidi 44:23-26
Awon Akosori / Ese Iranti
“Dide fun iranlowo wa, ki o si ra wa pada nitori aanu Re” (Orin Dafidi 44:26)
Itupale
I gbe aye maa n sise lori awon ilana kan ati pe lati won, mu mu awon abajade to nitumo se le je pelu wahala/jakadi. Oluko ni mimo ninu awon ilana lati mu ki ohun gbo gbo a se. Beeni, awon ojuse kan se wa ni o nikan so, sugbon bi akoko kan wa ninu igbesi aye eniyan ti o nilo isise-papo tabi atileyin lati la awon iranlowo aye ko ja.
Awon Koko Adura
- Jesu Oluwa, dide ki o si ran mi lowo ki oju ma baa ti mi.
- Emi Mimo, ran mi lowo lati mo pataki iranlowo Re ati O si gba mi ni igbega mo to tan, ni oruko Jesu.
- Gbadura fun agbara ati iwalaaye Ọlọrun sii ní Ẹkun gbodo olutimẹhin ti ijọ Aposteli Kristi, ninu aye baba wa, Alabojuto Ekun yii, awọn oṣiṣẹ miran ati awọn ijọ ni oniruuru awọn ipile, ni orukọ Jesu.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Jona 3-4
Sep
29
Omi Iye
Awon Wakati Adura Didun
Omi Iye
Awon Wakati Adura Didun
Ojo Isegun (Tuesday), September 29, 2026
Orin: I.O.I CAC 577 · Ka: Heberu 4:16; Isaiah 55:6-7
Awon Akosori / Ese Iranti
“Nje Peteru omo Johanu jumo goke lo si tempili ni wakati adura, ti ise wakati kesan ojo” (Ise 3:1)
Itupale
Nso ti n maa n bi lati ibi ikoko adura ni odun 1930, ti Babalola waye iju Efon Alaye, ti o tumo si irun irin gbagara, kokoro kan pataki ni ninu aye wa. Olorun. Isoro tooto maa n bere nigba tokan tokan ba ti ara gbo ro pe ti idapada awon akoko ni oye ilana yii, won ni pa Awon akoko adura ti a gbekale mo ninu ise ninu idasile oju to dara fun isodotu na se.
Awon Koko Adura
- Baba, tun ipongbe mi fun adura igba gbo gbo ati eyi to gbo na se, ki Emi le ni ibagbepo to jinle pelu Re.
- Emi Mimo, ko mi le ni maa gbadura pelu Olorun leke ja won ohun idiwo, ko Emi le maa nnu isoji.
- Gbadura fun eka Ile Ise Ihinrere Ile Okere, ti Ijo Aposteli Kristi, Oludari ati awon osise miran lati, maa nipa ninu jijere okan ati ikede ihinrere si i, ni oruko Jesu.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Obadiah 1; Jona 1-2
Sep
28
Omi Iye
Awon Orin Iyin Si Olorun
Omi Iye
Awon Orin Iyin Si Olorun
Ojo Aje (Monday), September 28, 2026
Orin: I.O.I CAC Onir. 8 · Ka: Orin Dafidi 47:1-9
Awon Akosori / Ese Iranti
“E korin iyin si Olorun, e korin yin! E korin iyin si Oba wa, e korin iyin!” (Orin Dafidi 47:6)
Itupale
Awon orin iyin je okan pataki lara ijosin. Nje ko je iyalenu pe wa lati maa orin si? Aseda aye n beere lowo pe Olorun n gbe ninu awon so fun wa pe Olorun n gbe ninu iyin awon eni Re. A seda wa lati maa yin ati lati maa fi ope fun Un. Yinyin Olorun ko ni tabi sugbon lati se. Gbogbo ti a n pe gbo gbo eniyan si ni a pe lati maa fogun fun Un (O. D. 117:1-2).
Awon Koko Adura
- Jesu Oluwa, se mi ni olo iyin fun ogo Re.
- Emi ti yoo maa yin Olorun nigba gbo gbo bi Dafidi igbe s i ni oruko Jesu.
- Jesu Oluwa, ran awon ijo wa lowo lati maa gbe kikorin nipa temi ati awon Kristieni ti yoo fogo fun oruko Re jeke.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Amosi 7-9
Sep
27
Omi Iye
Oro Ti O Sanra
Omi Iye
Oro Ti O Sanra
Ojo Aiku (Sunday), September 27, 2026
Orin: I.O.I CAC 714 · Ka: 1 Awon Oba 3:1-15
Awon Akosori / Ese Iranti
“Ati Abeli, oun pelu mu ninu akobi eran osin ani ninu awon ti o sanra. Oluwa si fi oju rere wo Abeli ati ore re” (Genesisi 4:4)
Itupale
Ibukun ohun iyanu to se iyebiye ninu igbe aye eniyan. Gbogbo eniyan lo n pongbe lati maa gbe oro Olorun ati lo lati maa jebutu maa lati o alarawa bi Olorun naa ni fun wa maa jebutu ipin ninu awon ti o fe lati gba ipin. Fun apere, Kaini naa ni fe lati fun mimu to kan naa ni Abeli ni fe gba fun Olorun, bi o tile je pe ore to kuna osuwon to dara ati tokasi. Ninu ege yii osuwon to dara ko togasi. Ninu ege nikan sugbon ati dara pelu iwa ati ipo ore, le yin ohun o mu ore naa idajo lori Olorun, le yin gbogbo Ohunkohun ti a ba fifun Un gbo o je eyii o dara julo. Olorun ni reti oswon to dara ninu ijosin, ise, ati awon ebun wa.
Awon Koko Adura
- Jesu Oluwa, mo dupe lowo Re fun ohun gbogbo ti O ti fi fun mi nipa oore ofe, gege bi ami ibukum Re.
- Jesu Oluwa, mo beere fun oore ofe lati mu okan to gbooro fun idupe dagba fun gbogbo lowo toye lati maa igbagbo ninu igboran.
- Emi Mimo, ran awon onigbagbo lesemule ninu igbagbo to fogo fun Olorun.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Amosi 4-6
Sep
26
Omi Iye
Ipongbe Nipa Temi
Omi Iye
Ipongbe Nipa Temi
Ojo Abameta (Saturday), September 26, 2026
Orin: I.O.I CAC 770 · Ka: Johanu 20:1-18
Awon Akosori / Ese Iranti
“Alabukun fun ni awon eniti ebi n pa ati ti oungbe n gbe sipa ododo, nitori won o yo” (Matiu 5:6)
Itupale
Ipongbe nipa temi je ohun to jinle, pipongbe nipa temi to n ru eniyan soke lati maa wa Olorun pelu itara. Bibeli gboriyin fun ebi/ipongbe yii ninu aye awon eniyan kan, gege bi a ti ko o pe: "Alabukun fun ni awon eniti ebi n pa ati ti ongbe n gbe sipa ododo". Onisaamu safihan imolara yii nigba ti o wipe: Bi agbonrin ti maa n mi hele sipado omi, Olorun, beeni okan mi n mi hele si O, ongbe Olorun n gbe okan mi, ti Olorun alaaye" (O.Daf. 42: 1-2).
Awon Koko Adura
- Jesu Oluwa, ru mi soke lati ri ati lati mo O jinle ju bi mo ti mo O tele lo.
- Je ki ebi ati ipongbe fun ododo maa dagbasoke ju ti ateyinwa lo ninu mi, Oluwa.
- So fun Olorun lati seranwo fun alakoso eto isakoso ati awon osise ijo nla yii lati mu agbekale/isakoso dagbasoke lo si ibi giga, ni oruko Jesu.
Afikun Ibi Kika Fun Oni: Amosi 1-3